Oniwaasu 2: 12 – 16
Orin: (YHB 291)
– A! mba le legberun ahon.
Adura: Olorun Eleda
ati Oloore mi, ngo mo bi nba ti yin O to? Mo dupe o.
Ifaara: Ninu
Ogbon ati Omugo, ewo lo ye ki eniyan ni?.
(Ese. 12) – Se afayo bi Solomoni Oba ti ro ninu okan re nipa jije
ologbon tabi omugo.
1. Mo si yi ara mi pada lati wo
ogbon ati ise omugo.
2. Nitoripe kinni Okunrin naa
ti nbo leyin oba yoo le se?
3. A fi eyi ti a ti se tan ni
yoo se.
(Ese. 13 – 14) – Se afayo iyato ti Solomoni oba afayo ninu ogbon ati omugo.
1. Nigba naa ni mo ri pe ogbon
ta were (Omugo) yo bi imole ti ta okunkun yo.
2. Oju ologbon n be ni ori re,
Sugbon omugo n rin ni okunkun.
3. Emi si mo wipe abayori kanna
ni gbogbo won.
(Ese. 15 – 16) – Se afayo awon ohun ti yoo pari Ologbon ati Omugo bi
Solomoni ti rii.
1. Nigba naa ni mo wi ni aya mi
pe.
2. Bi o ti n se asiwere
(Omugo), bee ni n se si emi tikalara mi
3. Nitori kinni emi se gbon ju?
nigba naa ni mo wi ni okna mi pe assan ni eyi pelu
4. Nitoripe iranti ko si fun
ologbon pelu omugo laelae
5. Ki a wo o pe bi akoko ti
koja, bee ni ojo ti n bo
6. A o gbagbe gbogbo re,
ologbom ha se n ku bi i omugo.
Akiyesi.
- Ogbon ti ko ba ni iberu Olorun ninu je ti eniyanati aye. Iru ogbon bee a si maa pa ologbon lara. (Orin
Dafidi 111:10)
- Ogbon n ko ipa ti o po ninu aye eniyan
Ø
Ogbon ni a fi n kole (Owe 24:3).
Ø
Ogbon sanju agbara lo, (Oniwaasu 9:16).
Ø
Ogbon ni a fi n soro lawujo (Owe 31:26).
Ø
Ogbon ati io wonu ara won (Jakobu 3:13).
- Ati Ogbon ati Omugo, bi a ti bi won sinu aye, bee ni iku yoo tun mu won lo (Oniwaasu 2:16)
Akoko Adura.
- Loruko Jesu, OLUWA mi, fun mi ni emi ogbon ti yoo ni
iberu Re lokan bii ti Josefu ati Danieli.
- Loruko Jesu, OLUWA mi, awon akonilogbon jona ko gbodo
ri mi gbese lojo aye mi.
- Ran mi lowo fun awon Omo ti o fi fun mi to ni emi
ogbon ti yoo mi enikookan won tayo ni rere loruko Jesu.
- “Ologbon laye, ko ni sinmi, beeni Omugo eniyan ko ri
aye wa” OLUWA mi, fun mi ni ogbon ti o ni isinmi ati suuru, ki n le wulo
fun Ogo ati Ola Re loruko Jesu.
No comments:
Post a Comment