Monday, July 7, 2014

ASIRI OTITO NIPA IGBALA AWON OMO ISRAELI



Bibeli Kika  (Romu 11: 25 – 36)    
   

(Ese 25 - 27). – Se afayo alaye die ti o fi otito nipa Igbala Israeli han.
  1. Paulu ko fe ki awon ara Romu wa ni okunkun si otito nipa Igbala awon omo Israeli – V 25
  2. Paulu ko fe ki awon ara Romu ro wipe awon nikan ni Olorun seto Igbala Re fun – V. 25
  3. Olorun ti se ipinu Re pe lati Sioni ni Igbala yoo ti jade wa si gbogbo eniyan – V. 26
  4. Olorun ti ba won da majemu Re lati dari ese won ji won, tabi mu se won kuro – V. 27

(Ese 28 – 29). – Se afayo AGBEKALE bi Olorun se gba Israeli la.
  1. Nipase awon baba won Olorun ti so won di ayanfe, ki I se nipa se itankale Ihinrere. V. 28.
  2. Olorun nawo ipe Re ti ko yipada si won lati fi pe won (Majemu ayeraye) – V. 29.

(Ese. 30 - 32)Se afayo IYATO bi Igbala ti awon ara Romu si ti Israeli.
  1. Nipa aanu Olorun ni awon ara romu fi ri Igbala gba (nipa itankalae ihinrere). – V. 30
  2. Bi awon Israeli ba tile je alaegboran, aanu Olorun si duro fun won – V 31.
  3. Awon ara Romu je alaegboran Sugbon a fi aanu Olorun gba won la – V 32.

(Ese. 33 – 36)Se afayo TITOBI OLORUN ti O fi gbanila, ti o ye fun Iyin ati Ogo.
  1. Titobi Olorun je awamaridi o kun fun oro ijinle ati ogbon – V. 33
  2. Titobi Olorun ko nilo imoran awa eniyan ki O to lo titobi Re. – v. 34
  3. Titobi Olorun ko nilo iranlowo awa eniyan ki O to fi titobi Re joba. V. 34.
  4. Lati inu titobi Olorun n I ipa ati agbara fun ohun gbogbo ti n wa – V. 36.
  5. Ti Olorun ni ogo ati iyin wa fun lae ati lae lae. Ko si afiwe Re.
AKIYESI.
  1. Asiri bi Olorun se je Olorun, ko fi han eniyan. Eniyan ko si le mo o titi lae lae.
  2. Bi a ba gba eniyan la kuro ninu ese re, aanu Olorun lo ri gba, ki i se eto re. Ki iru eni bee mo wipe Oun nikan ko ni aanu yi wa fun. Aanu Olorun wa fun gbogbo eniyan ti o ba gbagbo (Rom 10:11-12; Gala. 3:28; Ise Awon Aposteli 10:36)
  3. Bi Olorun ba wo wa se laanu, o di ojuse ti awa naa lati ma jeki aanu Re bo sonu kuro lowo wa(I Peteru 5:8 – 11) Bi Olorun ba gba wa la, Ihinrere Igbala naa di ise wa lati tan – an de odo awon alaegbagbo (Ise Awon Aposteli 1:8; 4:12; II Korinti 5:17 – 20)

Friday, July 4, 2014

IWA ATI ISE: AMUYE AYE KRISTIANI



Bibeli kika-: (Jakobu 1:19).
Ifaara:         Ti ko ba si iwa ati ise, nje a le mo eniti o fewa tabi ti a wa naa feran.
(Vs. 19 – 20) – Se afayo awon ona ti a le gba lo iwa ati ise wa tabi ti iwa ati ise wa le fi wa han bi ati se je.
1.      Nipa bi a ba ti se gbo oro ati bi a ba se dahun si oro ti a gbo.
2.      Nipsa bi a ba se lora tabi yara lati binu si.
3.      Nitori ibinu eniyan ki i sise ododo Olorun.
(Vs. 21 – 22) – Nipa awon ona wo l le fi iwa ati ise wa jo kristiani.
1.      Nipa fifi gbogboeeri ati buburu  aseleke lele ni apa kan.
2.      Nipa fifi okan tutu gba oro naa ti a gbin ti o le gba okan la
3.      Nipa jije Oluso oro naa, kii se olugbo nikan, ki a maa tan ara wa je.
(Vs 23 – 24) – Se afayo apejuwe eniti Iwa ati ise re yato si oro naa ti o gbo.
1.      O dabi okunrin ti o sakiyesi oju ara re ninu awojiji.
2.      Loju kan naa o si gbagbe bi oun ti ri, o n ba tire lo.
(Vs 25 – 27) – Se afayo eniti o fi Iwa ati Ise re jo Kristiani bi oro naa ti o gbo.
1.      Iru eni bee yoo ma woo inu ofin pipe, ofin ominara ti yoo si duro ninu re.
2.      Iru eni bee ki se olugbo ti o gbagbe, bikose oluse ise oro naa.
3.      Iru eni bee yoo di alabukun fun ninu ise re.
4.      Iru eni bee yoo le ko ilo ahon re niijanu ninu isin re si Olorun.
5.      Iru eni bee yoo le sin Olorun ni mimo bi Olorun ti n fe.
6.      Iru eni bee yoo le mo bi aati bojuto awon alaeni gbogbo
7.      Iru eni bee yoo le pa ara re mo laelabawon.
Akiyesi.
  1. Ati eniti o je Omoleyin Kristi ati eniti ki i se e, Iwa ati Ise wa je ona ti a n fi n pew a ni eniyan, Mejeeji
yii la si le fi mo odiwon ife tabi ikorira wa si elomiran.
  1. Omoeyin Kristi gbodo wa jeki iwa ati ise oun je dara dara si gbogbo eniyan. Eyi ni yoo si ran ise ijeri ihinrere lowo (Matteu 5:43 – 48; Romu 12: 16 – 18).
  2. Bi awon aladugbo wa ba tile n ba wa wa wahala, iwa ati ise wa (bi Omoeyin Kristi) gbodo so fun won pe awa ko ni n won n se e si bikose si Olorun, Eniti o kun oju osuwon lati gba ija wa ja, ti yoo gba ejo wa wi (Eksodu 14:18, 25)
  3. Ninu ijakadi aye, iwa ati ise wa gbodo fi wa han bi Omoeyin Kristi.
Akoko Adura.
  1. Jeki agbara imole Re maa se amona mi nigba gbogbo.
  2. Womi lagbara ti o to ti n go fi le si O titi opine mi mi loruko Jesu.
  3. Bi aye n gbogun, ti esu si n dode, nitori ti mo gba O gbo. Ma fi mi le esu lowo o.
  4. Oluwa, jeki odun yii je aluyo fun rere aye mi ati Idile mi
Oore – ofe Ifarada ti yori si ayo ati inu didun ninu Re Oluwa fi fun mi
Pilgrim that stay focus / Ar8n r8n zj0 8vzv9 ti oni zfoj5s5n
(Hebrew 12:12 – 15)
(V5) Oh LORD, You are a wonderful God and full of mercy. Accept my praises in jesus name / OL%WA mi, {l[run 8yanu ti o kun fun aanu ni {. Gba iyin mi loruk[ Jesu.
It is by Your mighty power and enduring mercy that kept me and my family safe from all sorts of hangers. Take my humble honour offer to You in Jesus name / Nipa avara nla ati aanu Rc ti o tojo ni o pa emi ati Idile mi m[ kuro ninu vovo ewu. Gba [la ati Ogo mi ti mo fi irele [kan mi mu wa fun { loruk[ Jesu.
Cause us to be more and continually offer our praises untoYou all the time / Jcki a le maa ridi ti a o fi le ma yiin { loruk[ Jesu.
(v.14) Others may forget, but let me, my family and every members of our church fasten our relationship with You, O! LORD, in Jesus name / Aw[n yooku le vzv3, suvon jcki emi, Idile mi ati aw[n {m[ ij[ wa le jcki okun ibatan wa pelu Rc OLUWA mi le di koko sii ju ateyinwa l[ loruk[ jesu.
Cause us to see the need to store up our treasures in heaven than in this temporary world. /Jcki a le ri idi lati le e to isura wa si [run ju ti aye yii ti o wa fun iva die l[.
Cause my glory to outshine faster and be of benefit even while I am in the world in Jesus name / Jcki Ogo aye mi tete bu jade ki o si ni ere ninu nivati mo si wa loke epc ni oruk[ Jesu.
(Vs. 12 -13) Because Jesus Christ had suffere ouside the gate / Nitori Jesu kristi ti jiya lcyin bode ilu:-
  1. Let His sacrificial blood make me holy / Jcki cjc Rc ti o fi rub[ s[ mi di mim[;
  2. Let go all the disgrace of my life / Jcki aw[n cgan aye mi di pipora kuro ninu aye mi.
  3. Let inposibilities of my life become possible to enable me stay focus / Jcki vovo ko see se aye maa di sise ki n le duro ninu afojusun mi vovo.
  4. Let all mockness of my life become a louder glory in my life for Your glory / Jcki vovoycyc aye mi di aycyc fun mi fun ogo ati Ola Rc;
  5. Empower me to breakthrough all barriers of live as from today in Jesus’ name / W[ mi lacara ti lalaja laye  alti oni l[ loruko Jesu.
  6. Burry all my shames outside the gate in Jesus’ name /Sin oku vovo itiju aye mi lcyin odi loruk[ Jesu ilu.
  7. As a pilgrim, cause me to stay focus and prosper in any thing I will be laying my hands as from today in Jesus’ name / Gcgc bi arin rin ajo, jcki n le duro ninu aw[n afojusun mi, si jcki adaw[le mi le naa y[ri sir ere loruk[ Jesu.

Wednesday, June 25, 2014

INTRODUCTION TO THE BOOK OF ROMANS.





            Paul wrote this Epistle to the Church in Rome. Neither Paul nor the other Church leaders like James and Peter had yet been to Rome. Most likely , the Roman Church had been established by believers who had been at Jerusalem for Pentecost (2:10) and travelers who had heard the Good News in other places and had brought it back to Rome for example Pricilla and Aquila – Acts 8:2, Romans 16:3 – 5
         
Paul wrote this Epistle to the Romans during His ministry in Corinth (Acts 20:3; Romans 15:12) to encourage the believers and to express his desire to visit them some day.
The Romans Church had no New Testament because the Gospel were not yet being circulated in their final written form. Thus, this Epistle may well have been the first piece of Christian literature the Roman believers had seen. It was written to both Jewish and Gentile Christian, it is a systematic presentation of the Christian faith.
         
Like an intelligent, articulate, and committed man of the Gospel, Paul presented the case for the gospel clearly and forthrightly in his Epistle to the believers in Rome. The believers were his brothers and sisters in Christ and he longed to see them face to face. He had never met most of them, yet he loved them. He sent his letter to introduce himself and to make a clear declaration of the faith.
         
Speaking directly to his Jewish brothers and sisters, Paul shares his concern for them and explain how the fit into God’s plan. God has made the way for Jews and Gentiles to be united in the body of Christ – both group can praise God for his wisdom and love. Paul explains what it means to live complete submission to Christ – using Spiritual gifts to serve others, genuinely loving others and being good citizens. Freedom must be guided by loves as we build each other up in the faith. He also stress unity, especially between Gentiles and Jews. He concludes by reviewing his reasons for writing, outlining his personal plans, greeting to his friends, and giving a few final thoughts and greetings from his traveling companions.
         
As we are reading and studying the book of Romans, we need to re – examine our commitment to Christ and reconfirm our relationship with other believers in Christ’s body.

“Therefore since, since we have been justified through faith, we have peace with God through our Lord Jesus Christ (5:1). For in the gospel a righteousness’ from God is recommended, a righteousness that is by FAITH, from first to last, just as it is written: “ the righteous will live by FAITH”- (1:17). I am not ashamed of the gospel, because it is the power of God for the salvation of every one who believes: first for the Jews then for the Gentile – (1:16)