Bibeli kika-: (Jakobu 1:19).
Ifaara: Ti
ko ba si iwa ati ise, nje a le mo eniti o fewa tabi ti a wa naa feran.
(Vs. 19 – 20) – Se afayo awon ona ti a le gba lo iwa ati ise wa tabi ti
iwa ati ise wa le fi wa han bi ati se je.
1.
Nipa bi a ba ti se gbo oro ati bi a ba se dahun si oro
ti a gbo.
2.
Nipsa bi a ba se lora tabi yara lati binu si.
3.
Nitori ibinu eniyan ki i sise ododo Olorun.
(Vs. 21 – 22) – Nipa awon ona wo
l le fi iwa ati ise wa jo kristiani.
1.
Nipa fifi gbogboeeri ati buburu aseleke lele ni apa kan.
2.
Nipa fifi okan tutu gba oro naa ti a gbin ti o le gba
okan la
3.
Nipa jije Oluso oro naa, kii se olugbo nikan, ki a maa
tan ara wa je.
(Vs 23 – 24) – Se afayo apejuwe
eniti Iwa ati ise re yato si oro naa ti o gbo.
1.
O dabi okunrin ti o sakiyesi oju ara re ninu awojiji.
2.
Loju kan naa o si gbagbe bi oun ti ri, o n ba tire lo.
(Vs 25 – 27) – Se afayo eniti o fi
Iwa ati Ise re jo Kristiani bi oro naa ti o gbo.
1.
Iru eni bee yoo ma woo inu ofin pipe, ofin ominara ti
yoo si duro ninu re.
2.
Iru eni bee ki se olugbo ti o gbagbe, bikose oluse ise
oro naa.
3.
Iru eni bee yoo di alabukun fun ninu ise re.
4.
Iru eni bee yoo le ko ilo ahon re niijanu ninu isin re
si Olorun.
5.
Iru eni bee yoo le sin Olorun ni mimo bi Olorun ti n
fe.
6.
Iru eni bee yoo le mo bi aati bojuto awon alaeni gbogbo
7.
Iru eni bee yoo le pa ara re mo laelabawon.
Akiyesi.
- Ati eniti o je Omoleyin Kristi ati eniti ki i se e, Iwa ati Ise wa je ona ti a n fi n pew a ni eniyan, Mejeeji
yii
la si le fi mo odiwon ife tabi ikorira wa si elomiran.
- Omoeyin Kristi gbodo wa jeki iwa ati ise oun je dara dara si gbogbo eniyan. Eyi ni yoo si ran ise ijeri ihinrere lowo (Matteu 5:43 – 48; Romu 12: 16 – 18).
- Bi awon aladugbo wa ba tile n ba wa wa wahala, iwa ati ise wa (bi Omoeyin Kristi) gbodo so fun won pe awa ko ni n won n se e si bikose si Olorun, Eniti o kun oju osuwon lati gba ija wa ja, ti yoo gba ejo wa wi (Eksodu 14:18, 25)
- Ninu ijakadi aye, iwa ati ise wa gbodo fi wa han bi Omoeyin Kristi.
Akoko Adura.
- Jeki agbara imole Re maa se amona mi nigba gbogbo.
- Womi lagbara ti o to ti n go fi le si O titi opine mi mi loruko Jesu.
- Bi aye n gbogun, ti esu si n dode, nitori ti mo gba O gbo. Ma fi mi le esu lowo o.
- Oluwa, jeki odun yii je aluyo fun rere aye mi ati Idile mi
No comments:
Post a Comment